KOKORO SI AWORAN AWON
IGBA
Igba (Aseko Awon Opin)
A.
Aiye
ti o tiwa Iran Akoko (2 Peteru 3:6, Genesis
6:11-13)
B.
Aiye Buburu
isinsinyii Iran Ikeji (Galatia 1:4, 1 Johanu
5:19, Malaki 3:15)
C.
Aiye
to nbo Iran Keta (Heberu 2:5, 2 Peteru 3:13,
Efesu 1:10)
D.
Baba nla mejila (ise
awon Aposteli 7:8)
E.
Igba
awon juu (Deuteronomy 7:6, Orin dafidi
147:19-20)
F.
Igba
Iyin-rere (Marku 1:14-15, Ise awon aposteli
15:14, Matteu 24:14)
G.
Igba messia (1
Korinti 15:25, Ifihan 20:1-6)
H.
Awon
igba to nbo (Efesu 2:7, 3:21)
f. Akoko wahala Isreli nigba Ikore
Ara Juu: Ipinya Alikama at Iyangbo (Luku
3:16-17).
S.
Akoko Wahala ti
agbaye nigba ikore iyin-rere: Ipinya alikama at
Epo (Matteu 13:30, 38:40, Ifihan 14:15, 18)
T.
Iku keji igba
die, pipinya aguntan, Ewure (Matteu 25:31-32,
Ifihan 20:7-10, 14-15, 1 Korinti. 15:26)
Awon ila (Awon Igbese si ogo)
K.
Ipo ogo ti orun ati
ojuse agbara (Filippi 2:9-11)(Ifihan 3:21)
L.
Ipo bibi ti emi (Johannu
3:8, 1 Johannu 3:2)
M.
Ipo atunbi nipa ti
emi (Romu 12:1, Peteru 1:3-4)
N.
Ipo oju rere olorun
(si eniyan) (Jakobu 2:23, 5:8-9,19)
P.
Ipo riri oju rere
olorun (lefitiku 16:30, Heberu 9:7-10)
R.
Ipo ese ati iwa
buburu (Romu 5:12, Isaiah 64:6, Romu 10:3)
Oke (Egbegbe Awon Eniyan)
a. Adamu ni eda pipe (Genesisi
1:27,31)
b.
Isubu Adamu ati iru awon omo re,
ki o to di kikun omi (Gen. 6:5)
c.
Ni Olukuluku awon eniti a kaye
igbani (Romu 4:2-3, Esekieli 14:20, Heberu 11)
d.
Gbogbo eniyan lati ekun omi si
igba messia Romu 5:12, 1 Johannu 5:19
e.
Isreali ti ara di idalare apere
gegebi Orile-ede (Lefitiku 16:33-34, Heberu
10:1)
Kristi
g.
Jesu ni odun 30, oje eda
pipe(Heberu10:5, Johannu1:29-32)
h.
Jesu eni abi nipa ti emi ni
jodani (Matteu 28:18, Johannu 5:26)
i.
Jesu, jidide bi eni ti orun (Matteu
28:18, Johannu 5:26)
k. Jesu 40 ojo lehin ajinde, ninu ogo ti orun (Ise
awon Aposteli 1:19, Heberu 9:14)
l.
Jesu, ni gba iyin-rere, ojoko pelu baba lori ite
(Heberu 6:20, 10:12, ifihan 3:21)
Kristiani ni igba iyein-rere
m.
Egbe awon atunbi
nipa ti emi ti o wa di ajo nla (1
korinti 3:11, 15)
n.
Egbe awon atunbi
nipa ti emi ti o di iyawo ninu Kristi (Romu
12:1-2, Peteru 2:9-10, Galatia 5:22-25)
p.
Awon onigbagbo, ti
ko yara soto lekunrere (Marku 9:41, ise awon
Aposteli 26:27-28, Matteu 22:14)
q.
Epo, alosi
ile-ijosin tikinse onigbagbo, alaganbagebe (Matteu
13:38, 15:8, 9)
Ni sise Ikore
igba iyinrere
r.
Jesu,
ni ipada bo re lekeji (Johannu 14:13,
Tessalonika 4:16)
s.
Agbo
kekere, ya soto kuro lara babiloni (Ifihan
18:15) Tesalonika 4:16-17)
t.
Opo
eniyan kuna lati gba ere tio tayo (Ifihan
7:13-17, 1 Korinti 3:13,15)
u.
Babiloni, Ijo tio ni oruko lasan, kuna: Awon kan
seku lori ila N, awon toku jakule sisale (Ifihan
3:15-16, 16:19).
v.
Babiloni, ipinle-ese agabangebe ijo oloruko
lasan, jakule si ila R, pelu awon alaigbagbo (Ifihan
18:2, Matteu 24:51)
Ni Sise Igba
Egberun Odun
w. Kristi ti a se logo, ori ati ara (Ifihan 19:7, 21:2)
x. Egbe
ti Kristi ti a se logo, njoba (1 Johannu 3:2,
Juda 14 Ifihan 3:21, 20:4, 6)
y.
Egbe Ajo nla (Orin dafidi 45:14, ifihan 7:9-10,
13-17,19:1)
z.
Isreali ti ara pada si ipo olokiki (Romu 11:25,
sekariah 18:13-23)
W.
Araiye pada si ipo pipe ati irepo pelu olorun (Ifihan
21:1-4 Isaiah 35) |